Àìsáyà 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Alágbára Ísírẹ́lì, kéde pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Mi ò ní fàyè gba àwọn elénìní mi mọ́,Màá sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.+ Àìsáyà 59:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.
24 Torí náà, Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Alágbára Ísírẹ́lì, kéde pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Mi ò ní fàyè gba àwọn elénìní mi mọ́,Màá sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.+
18 Ó máa san wọ́n lẹ́san ohun tí wọ́n ṣe:+ Ó máa bínú sí àwọn elénìní rẹ̀, ó máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn ọ̀tá rẹ̀.+ Ó sì máa san ohun tó yẹ àwọn erékùṣù fún wọn.