ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 1:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àwọn ìyàwó yín, àwọn ọmọ yín àtàwọn ẹran ọ̀sìn yín á máa gbé ní ilẹ̀ tí Mósè fún yín ní apá ibí yìí* ní Jọ́dánì,+ àmọ́ kí gbogbo ẹ̀yin jagunjagun tó lákíkanjú+ sọdá ṣáájú àwọn arákùnrin yín, kí ẹ tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun.+ Kí ẹ ràn wọ́n lọ́wọ́ 15 títí Jèhófà fi máa fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi, bó ṣe ṣe fún yín, tí àwọn náà á sì gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún wọn. Kí ẹ wá pa dà sí ilẹ̀ tí wọ́n fún yín pé kí ẹ máa gbé, kí ẹ sì gbà á, ilẹ̀ tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín ní ìlà oòrùn Jọ́dánì.’”+

  • Jóṣúà 22:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhófà Ọlọ́run yín ti wá fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+ Torí náà, ẹ lè pa dà sí àgọ́ yín ní ilẹ̀ tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín pé kí ẹ jogún ní òdìkejì* Jọ́dánì.+

  • Jóṣúà 22:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìní pa dà lọ sí àgọ́ yín, pẹ̀lú ẹran ọ̀sìn tó pọ̀, fàdákà àti wúrà, bàbà àti irin àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ.+ Ẹ kó ìpín yín nínú ẹrù àwọn ọ̀tá yín,+ ẹ̀yin àtàwọn arákùnrin yín.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́