Léfítíkù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí wọ́n fi omi fọ ìfun rẹ̀ àti ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì mú kí gbogbo rẹ̀ rú èéfín lórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.*+
9 Kí wọ́n fi omi fọ ìfun rẹ̀ àti ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì mú kí gbogbo rẹ̀ rú èéfín lórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, tó ní òórùn dídùn.*+