-
1 Kíróníkà 5:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì,+ àkọ́bí Ísírẹ́lì nìyí. Òun ni àkọ́bí, àmọ́ torí pé ó kó ẹ̀gàn bá ibùsùn bàbá rẹ̀,*+ ẹ̀tọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí ni a fún àwọn ọmọ Jósẹ́fù+ ọmọ Ísírẹ́lì, torí náà, wọn ò kọ orúkọ rẹ̀ sínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn pé òun ni àkọ́bí. 2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.
-