Diutarónómì 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Pẹ̀lú àwọn ohun tó dáa ní ayé àti ohun tó kún inú rẹ̀,+Kí Ẹni tó ń gbé inú igi ẹlẹ́gùn-ún+ sì tẹ́wọ́ gbà á. Kí wọ́n wá sí orí Jósẹ́fù,Sí àtàrí ẹni tí a yà sọ́tọ̀ lára àwọn arákùnrin rẹ̀.+
16 Pẹ̀lú àwọn ohun tó dáa ní ayé àti ohun tó kún inú rẹ̀,+Kí Ẹni tó ń gbé inú igi ẹlẹ́gùn-ún+ sì tẹ́wọ́ gbà á. Kí wọ́n wá sí orí Jósẹ́fù,Sí àtàrí ẹni tí a yà sọ́tọ̀ lára àwọn arákùnrin rẹ̀.+