Diutarónómì 31:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Ọjọ́ ikú rẹ ti sún mọ́lé.+ Pe Jóṣúà, kí ẹ sì lọ síwájú* àgọ́ ìpàdé, kí n lè faṣẹ́ lé e lọ́wọ́.”+ Mósè àti Jóṣúà wá lọ síwájú àgọ́ ìpàdé. 1 Tímótì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Má fojú kéré ẹ̀bùn tí o ní, èyí tí a fún ọ nípasẹ̀ àsọtẹ́lẹ̀ nígbà tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà gbé ọwọ́ lé ọ.+
14 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Ọjọ́ ikú rẹ ti sún mọ́lé.+ Pe Jóṣúà, kí ẹ sì lọ síwájú* àgọ́ ìpàdé, kí n lè faṣẹ́ lé e lọ́wọ́.”+ Mósè àti Jóṣúà wá lọ síwájú àgọ́ ìpàdé.
14 Má fojú kéré ẹ̀bùn tí o ní, èyí tí a fún ọ nípasẹ̀ àsọtẹ́lẹ̀ nígbà tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà gbé ọwọ́ lé ọ.+