-
Diutarónómì 4:45, 46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Èyí ni àwọn ìrántí, àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí Mósè fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Íjíbítì,+ 46 ní agbègbè Jọ́dánì, ní àfonífojì tó dojú kọ Bẹti-péórì,+ ní ilẹ̀ Síhónì ọba àwọn Ámórì, tó ń gbé ní Hẹ́ṣíbónì,+ ẹni tí Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Íjíbítì.+
-