Sáàmù 147:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ fún Jékọ́bù,Ó sọ àwọn ìlànà rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ fún Ísírẹ́lì.+ 20 Kò ṣe bẹ́ẹ̀ fún orílẹ̀-èdè míì;+Wọn ò mọ nǹkan kan nípa ìdájọ́ rẹ̀. Ẹ yin Jáà!*+
19 Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ fún Jékọ́bù,Ó sọ àwọn ìlànà rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ fún Ísírẹ́lì.+ 20 Kò ṣe bẹ́ẹ̀ fún orílẹ̀-èdè míì;+Wọn ò mọ nǹkan kan nípa ìdájọ́ rẹ̀. Ẹ yin Jáà!*+