30 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Dánì gbé ère gbígbẹ́ náà+ kalẹ̀ fún ara wọn, Jónátánì+ ọmọ Gẹ́ṣómù,+ ọmọ Mósè àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì di àlùfáà fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Dánì títí di ọjọ́ tí àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà fi lọ sí ìgbèkùn.
7 Ó gbé ère òpó òrìṣà*+ tó gbẹ́ wá sínú ilé tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ fún Dáfídì àti Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀ pé: “Inú ilé yìí àti ní Jerúsálẹ́mù, tí mo ti yàn nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì, ni màá fi orúkọ mi sí títí láé.+