Àwọn Onídàájọ́ 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Yàtọ̀ síyẹn, Míkà fiṣẹ́ lé ọmọ Léfì náà lọ́wọ́* pé kó di àlùfáà rẹ̀,+ ó sì ń gbé ní ilé Míkà.