Nọ́ńbà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+ Àwọn Onídàájọ́ 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkùnrin tó ń jẹ́ Míkà yìí ní ilé kan tó kó àwọn ọlọ́run rẹ̀ sí, ó ṣe éfódì kan+ àti àwọn ère tẹ́ráfímù,*+ ó sì yan* ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ pé kó jẹ́ àlùfáà rẹ̀.+
10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+
5 Ọkùnrin tó ń jẹ́ Míkà yìí ní ilé kan tó kó àwọn ọlọ́run rẹ̀ sí, ó ṣe éfódì kan+ àti àwọn ère tẹ́ráfímù,*+ ó sì yan* ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ pé kó jẹ́ àlùfáà rẹ̀.+