ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 3:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+

  • Diutarónómì 12:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ mú wá sí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run yín yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà,+ ìyẹn àwọn ẹbọ sísun yín, àwọn ẹbọ yín, àwọn ìdá mẹ́wàá yín,+ ọrẹ látọwọ́ yín àti gbogbo ọrẹ tí ẹ jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà.

  • Diutarónómì 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kí ẹ rí i pé ẹ ò rú àwọn ẹbọ sísun yín níbòmíì tí ẹ bá rí.+

  • 2 Kíróníkà 13:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 “Ní báyìí, ẹ rò pé ẹ lè dojú kọ ìjọba Jèhófà tó wà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Dáfídì, torí pé ẹ pọ̀ jù wọ́n lọ, ẹ sì ní àwọn ère ọmọ màlúù wúrà tí Jèróbóámù fi ṣe àwọn ọlọ́run fún yín.+ 9 Ṣebí ẹ ti lé àwọn àlùfáà Jèhófà jáde,+ ìyẹn àwọn àtọmọdọ́mọ Áárónì àti àwọn ọmọ Léfì, tí ẹ sì yan àwọn àlùfáà tiyín bí àwọn èèyàn ilẹ̀ míì ti ń ṣe?+ Ẹni tó bá mú akọ ọmọ màlúù kan àti àgbò méje wá* lè di àlùfáà àwọn ohun tí kì í ṣe ọlọ́run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́