ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 18:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “‘Ẹ má fi èyíkéyìí nínú àwọn nǹkan yìí sọ ara yín di aláìmọ́, torí gbogbo àwọn nǹkan yìí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí mo fẹ́ lé kúrò níwájú yín fi sọ ara wọn di aláìmọ́.+

  • Léfítíkù 18:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Kí ilẹ̀ náà má bàa pọ̀ yín jáde torí pé ẹ sọ ọ́ di ẹlẹ́gbin, bó ṣe máa pọ àwọn orílẹ̀-èdè tó wà ṣáájú yín jáde.

  • Léfítíkù 26:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “‘Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, tí ẹ ò bá fetí sí mi, tí ẹ ṣì ń kẹ̀yìn sí mi,

  • Léfítíkù 26:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Èmi fúnra mi yóò mú kí ilẹ̀ náà di ahoro,+ àwọn ọ̀tá yín tó ń gbé ibẹ̀ yóò sì máa wò ó tìyanutìyanu.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́