Diutarónómì 28:62 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé o ti pọ̀ rẹpẹtẹ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run,+ ìwọ̀nba ló máa ṣẹ́ kù+ lára rẹ, torí pé o ò fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run rẹ.
62 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé o ti pọ̀ rẹpẹtẹ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run,+ ìwọ̀nba ló máa ṣẹ́ kù+ lára rẹ, torí pé o ò fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run rẹ.