Diutarónómì 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà máa tú yín ká sáàárín àwọn èèyàn,+ díẹ̀ nínú yín ló sì máa ṣẹ́ kù+ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa lé yín lọ.
27 Jèhófà máa tú yín ká sáàárín àwọn èèyàn,+ díẹ̀ nínú yín ló sì máa ṣẹ́ kù+ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa lé yín lọ.