ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+

  • Diutarónómì 28:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Jèhófà máa lé ìwọ àti ọba tí o bá fi jẹ lórí ara rẹ lọ sí orílẹ̀-èdè tí ìwọ àtàwọn baba ńlá rẹ kò mọ̀,+ o sì máa sin àwọn ọlọ́run míì níbẹ̀, àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi igi àti òkúta+ ṣe.

  • Jeremáyà 16:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí náà, màá lé yín jáde kúrò ní ilẹ̀ yìí sí ilẹ̀ tí ẹ̀yin tàbí àwọn baba ńlá yín kò mọ̀,+ ibẹ̀ ni ẹ ó ti sin àwọn ọlọ́run míì tọ̀sántòru,+ torí mi ò ní ṣojú rere sí yín.”’

  • Ìsíkíẹ́lì 20:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 “Ní tìrẹ, ìwọ ilé Ísírẹ́lì, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Kí kálukú yín lọ sin àwọn òrìṣà ẹ̀gbin rẹ̀.+ Àmọ́, tí ẹ kò bá fetí sí mi lẹ́yìn náà, ẹ ò ní lè fi àwọn ẹbọ yín àti àwọn òrìṣà ẹ̀gbin yín kó ẹ̀gàn bá orúkọ mímọ́ mi mọ́.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́