-
2 Kíróníkà 33:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nítorí náà, Jèhófà mú kí àwọn olórí ọmọ ogun ọba Ásíríà wá gbéjà kò wọ́n, wọ́n fi ìwọ̀ mú Mánásè,* wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà méjì dè é, wọ́n sì mú un lọ sí Bábílónì.
-