Hósíà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 A ó dá Samáríà lẹ́bi,+ torí pé ó ti ṣọ̀tẹ̀ sí Ọlọ́run rẹ̀.+ Idà yóò sì pa wọ́n,+A ó ṣán àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀,A ó sì la inú àwọn aboyún wọn.”
16 A ó dá Samáríà lẹ́bi,+ torí pé ó ti ṣọ̀tẹ̀ sí Ọlọ́run rẹ̀.+ Idà yóò sì pa wọ́n,+A ó ṣán àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀,A ó sì la inú àwọn aboyún wọn.”