Nọ́ńbà 35:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ẹ yan ìlú mẹ́ta ní apá ibí yìí ní Jọ́dánì,+ kí ẹ sì yan ìlú mẹ́ta ní ilẹ̀ Kénáánì+ láti fi ṣe ìlú ààbò.
14 Kí ẹ yan ìlú mẹ́ta ní apá ibí yìí ní Jọ́dánì,+ kí ẹ sì yan ìlú mẹ́ta ní ilẹ̀ Kénáánì+ láti fi ṣe ìlú ààbò.