Jóṣúà 21:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Látinú ìpín ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè, wọ́n fún àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ tí wọ́n jẹ́ ìdílé ọmọ Léfì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ, ìyẹn Gólánì+ ní Báṣánì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Bééṣítérà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú méjì.
27 Látinú ìpín ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè, wọ́n fún àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ tí wọ́n jẹ́ ìdílé ọmọ Léfì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ, ìyẹn Gólánì+ ní Báṣánì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Bééṣítérà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú méjì.