Jóṣúà 21:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n fún àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ ní ìlú mẹ́tàlá (13) látinú ìpín àwọn ìdílé ẹ̀yà Ísákà, ẹ̀yà Áṣérì, ẹ̀yà Náfútálì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ní Báṣánì.+
6 Wọ́n fún àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ ní ìlú mẹ́tàlá (13) látinú ìpín àwọn ìdílé ẹ̀yà Ísákà, ẹ̀yà Áṣérì, ẹ̀yà Náfútálì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ní Báṣánì.+