-
1 Kíróníkà 6:62Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
62 Wọ́n fún àwọn ọmọ Gẹ́ṣómù àti àwọn ìdílé wọn ní ìlú mẹ́tàlá (13) látinú ẹ̀yà Ísákà, ẹ̀yà Áṣérì, ẹ̀yà Náfútálì àti ẹ̀yà Mánásè ní Báṣánì.+
-