Ẹ́kísódù 33:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín,+ màá sì lé àwọn ọmọ Kénáánì kúrò, pẹ̀lú àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+ Jóṣúà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jóṣúà sì sọ pé: “Báyìí lẹ ṣe máa mọ̀ pé Ọlọ́run alààyè kan wà láàárín yín,+ ó sì dájú pé ó máa lé àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Hífì, àwọn Pérísì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Ámórì àti àwọn ará Jébúsì kúrò níwájú yín.+
2 Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín,+ màá sì lé àwọn ọmọ Kénáánì kúrò, pẹ̀lú àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+
10 Jóṣúà sì sọ pé: “Báyìí lẹ ṣe máa mọ̀ pé Ọlọ́run alààyè kan wà láàárín yín,+ ó sì dájú pé ó máa lé àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Hífì, àwọn Pérísì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Ámórì àti àwọn ará Jébúsì kúrò níwájú yín.+