ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 27:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ ra ẹnikẹ́ni tí a máa pa run pa dà.+ Ṣe ni kí ẹ pa á.+

  • Jóṣúà 6:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Kí ẹ pa ìlú náà run àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀;+ Jèhófà ló ni gbogbo rẹ̀. Ráhábù+ aṣẹ́wó nìkan ni kí ẹ dá ẹ̀mí rẹ̀ sí, òun àti gbogbo àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ilé, torí ó fi àwọn tí a rán níṣẹ́ pa mọ́.+

  • Jóṣúà 10:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Jóṣúà gba Mákédà+ ní ọjọ́ yẹn, ó sì fi idà pa á run. Ó pa ọba rẹ̀ àti gbogbo àwọn* tó ń gbé ibẹ̀ run, kò ṣẹ́ ẹnì kankan kù.+ Ohun tó ṣe sí ọba Jẹ́ríkò gẹ́lẹ́ ló ṣe sí ọba Mákédà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́