Òwe 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní ti àwọn ẹni burúkú, a ó pa wọ́n run kúrò ní ayé,+Ní ti àwọn oníbékebèke, a ó fà wọ́n tu kúrò nínú rẹ̀.+ 2 Pétérù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọ̀rọ̀ yẹn kan náà la fi tọ́jú àwọn ọ̀run àti ayé tó wà báyìí pa mọ́ de iná, a sì ń fi wọ́n pa mọ́ de ọjọ́ ìdájọ́ àti ti ìparun àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+
22 Ní ti àwọn ẹni burúkú, a ó pa wọ́n run kúrò ní ayé,+Ní ti àwọn oníbékebèke, a ó fà wọ́n tu kúrò nínú rẹ̀.+
7 Ọ̀rọ̀ yẹn kan náà la fi tọ́jú àwọn ọ̀run àti ayé tó wà báyìí pa mọ́ de iná, a sì ń fi wọ́n pa mọ́ de ọjọ́ ìdájọ́ àti ti ìparun àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.+