-
Diutarónómì 7:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ ó máa fi ìparun san ẹ̀san fún àwọn tó kórìíra rẹ̀ ní tààràtà.+ Kò ní jáfara láti fìyà jẹ àwọn tó kórìíra rẹ̀; ó máa san wọ́n lẹ́san lójúkojú.
-
-
2 Tẹsalóníkà 1:7-9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àmọ́ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ní ìpọ́njú máa rí ìtura gbà pẹ̀lú wa nígbà ìfihàn Jésù Olúwa+ láti ọ̀run pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ alágbára+ 8 nínú iná tó ń jó fòfò, bó ṣe ń mú ẹ̀san wá sórí àwọn tí kò mọ Ọlọ́run àti àwọn tí kò ṣègbọràn sí ìhìn rere nípa Jésù Olúwa wa.+ 9 Àwọn yìí máa fara gbá ìyà ìdájọ́ ìparun ayérayé+ láti iwájú Olúwa àti látinú ògo agbára rẹ̀,
-