-
Ẹ́kísódù 23:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Kí wọ́n má ṣe gbé ní ilẹ̀ yín, kí wọ́n má bàa mú kí ẹ ṣẹ̀ mí. Tí ẹ bá lọ sin àwọn ọlọ́run wọn, ó dájú pé yóò di ìdẹkùn fún yín.”+
-
-
Diutarónómì 12:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 rí i pé o ò kó sí ìdẹkùn lẹ́yìn tí wọ́n bá pa run kúrò níwájú rẹ. Má ṣe béèrè nípa àwọn ọlọ́run wọn pé, ‘Báwo ni àwọn orílẹ̀-èdè yìí ṣe máa ń sin àwọn ọlọ́run wọn? Ohun tí wọ́n ṣe lèmi náà máa ṣe.’+
-