Diutarónómì 29:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 ‘Bí mo ṣe darí yín jálẹ̀ ogójì (40) ọdún nínú aginjù,+ aṣọ yín ò gbó mọ́ yín lára, bàtà yín ò sì gbó mọ́ yín lẹ́sẹ̀.+ Nehemáyà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ogójì (40) ọdún lo fi pèsè oúnjẹ fún wọn ní aginjù.+ Wọn ò ṣaláìní nǹkan kan. Aṣọ wọn ò gbó,+ ẹsẹ̀ wọn ò sì wú.
5 ‘Bí mo ṣe darí yín jálẹ̀ ogójì (40) ọdún nínú aginjù,+ aṣọ yín ò gbó mọ́ yín lára, bàtà yín ò sì gbó mọ́ yín lẹ́sẹ̀.+
21 Ogójì (40) ọdún lo fi pèsè oúnjẹ fún wọn ní aginjù.+ Wọn ò ṣaláìní nǹkan kan. Aṣọ wọn ò gbó,+ ẹsẹ̀ wọn ò sì wú.