Diutarónómì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kọkànlá, ọdún ogójì,+ Mósè bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ gbogbo ohun tí Jèhófà ní kó sọ fún wọn. Diutarónómì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Máa rántí ọ̀nà jíjìn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ rìn ní aginjù fún ogójì (40) ọdún yìí,+ kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, kó sì dán ọ wò,+ kó lè mọ ohun tó wà lọ́kàn rẹ,+ bóyá wàá pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ tàbí o ò ní pa wọ́n mọ́.
3 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kọkànlá, ọdún ogójì,+ Mósè bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ gbogbo ohun tí Jèhófà ní kó sọ fún wọn.
2 Máa rántí ọ̀nà jíjìn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ rìn ní aginjù fún ogójì (40) ọdún yìí,+ kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, kó sì dán ọ wò,+ kó lè mọ ohun tó wà lọ́kàn rẹ,+ bóyá wàá pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ tàbí o ò ní pa wọ́n mọ́.