Nọ́ńbà 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Onírúurú èèyàn*+ tó wà láàárín wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn hàn, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì náà tún wá ń sunkún, wọ́n sì ń sọ pé: “Ta ló máa fún wa ní ẹran jẹ?+ Nọ́ńbà 11:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Wọ́n wá pe ibẹ̀ ní Kiburoti-hátááfà,*+ torí ibẹ̀ ni wọ́n sin àwọn èèyàn tó hùwà wọ̀bìà torí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn sí.
4 Onírúurú èèyàn*+ tó wà láàárín wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn hàn, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì náà tún wá ń sunkún, wọ́n sì ń sọ pé: “Ta ló máa fún wa ní ẹran jẹ?+
34 Wọ́n wá pe ibẹ̀ ní Kiburoti-hátááfà,*+ torí ibẹ̀ ni wọ́n sin àwọn èèyàn tó hùwà wọ̀bìà torí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn sí.