Ẹ́kísódù 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn náà, Mósè yíjú pa dà, ó sì sọ̀ kalẹ̀ lórí òkè náà, ó gbé wàláà Ẹ̀rí méjì+ náà dání.+ Ọ̀rọ̀ tí a kọ wà lára wàláà náà ní ojú méjèèjì, ní iwájú àti ní ẹ̀yìn.
15 Lẹ́yìn náà, Mósè yíjú pa dà, ó sì sọ̀ kalẹ̀ lórí òkè náà, ó gbé wàláà Ẹ̀rí méjì+ náà dání.+ Ọ̀rọ̀ tí a kọ wà lára wàláà náà ní ojú méjèèjì, ní iwájú àti ní ẹ̀yìn.