5 Kí ẹ ṣáà rí i pé ẹ̀ ń tẹ̀ lé àṣẹ àti Òfin tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín,+ kí ẹ máa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀,+ kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ kí ẹ rọ̀ mọ́ ọn,+ kí ẹ sì máa fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara yín+ sìn ín.”+