Diutarónómì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O mọ̀ dáadáa lọ́kàn rẹ pé bí bàbá ṣe ń tọ́ ọmọ rẹ̀ sọ́nà ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ ń tọ́ ọ sọ́nà.+ Hébérù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 torí àwọn tí Jèhófà* nífẹ̀ẹ́ ló máa ń bá wí, àní, gbogbo ẹni tó gbà bí ọmọ ló máa ń nà lẹ́gba.”*+