ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 11:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà tí Sólómọ́nì darúgbó,+ àwọn ìyàwó rẹ̀ mú kí ọkàn rẹ̀ fà sí títẹ̀lé àwọn ọlọ́run míì,+ kò sì fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ bíi Dáfídì bàbá rẹ̀.

  • 2 Pétérù 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àmọ́ o, àwọn wòlíì èké tún wà láàárín àwọn èèyàn náà, bí àwọn olùkọ́ èké ṣe máa wà láàárín ẹ̀yin náà.+ Àwọn yìí máa dọ́gbọ́n mú àwọn ẹ̀ya ìsìn tó ń fa ìparun wọlé, wọ́n tiẹ̀ máa sẹ́ ẹni tó rà wọ́n pàápàá,+ wọ́n á sì mú ìparun wá sórí ara wọn ní kíákíá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́