Diutarónómì 19:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹlẹ́rìí kan ṣoṣo kò tó láti dá ẹnì kan lẹ́bi* àṣìṣe tàbí ẹ̀ṣẹ̀ èyíkéyìí tó dá.+ Nípa ẹ̀rí* ẹni méjì tàbí ẹ̀rí ẹni mẹ́ta, kí ẹ fìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀.+ 1 Tímótì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Má ṣe gba ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan àgbà ọkùnrin,* àfi tí ẹni méjì tàbí mẹ́ta bá jẹ́rìí sí i.+
15 “Ẹlẹ́rìí kan ṣoṣo kò tó láti dá ẹnì kan lẹ́bi* àṣìṣe tàbí ẹ̀ṣẹ̀ èyíkéyìí tó dá.+ Nípa ẹ̀rí* ẹni méjì tàbí ẹ̀rí ẹni mẹ́ta, kí ẹ fìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀.+