Nọ́ńbà 35:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i. Diutarónómì 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹni méjì tàbí mẹ́ta ni kó jẹ́rìí sí i,*+ kí ẹ tó pa ẹni tí ikú tọ́ sí. Ẹ ò gbọ́dọ̀ pa á tó bá jẹ́ pé ẹnì kan ṣoṣo ló jẹ́rìí sí i.+
30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i.
6 Ẹni méjì tàbí mẹ́ta ni kó jẹ́rìí sí i,*+ kí ẹ tó pa ẹni tí ikú tọ́ sí. Ẹ ò gbọ́dọ̀ pa á tó bá jẹ́ pé ẹnì kan ṣoṣo ló jẹ́rìí sí i.+