30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i.
15 “Ẹlẹ́rìí kan ṣoṣo kò tó láti dá ẹnì kan lẹ́bi* àṣìṣe tàbí ẹ̀ṣẹ̀ èyíkéyìí tó dá.+ Nípa ẹ̀rí* ẹni méjì tàbí ẹ̀rí ẹni mẹ́ta, kí ẹ fìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀.+