-
Diutarónómì 26:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí o wá máa yọ̀ torí gbogbo nǹkan rere tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fún ìwọ àti agbo ilé rẹ, ìwọ àti ọmọ Léfì àti àjèjì tó bá wà láàárín rẹ.+
-