ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Jèhófà wá sọ fún Mósè àti Áárónì pé, “Àṣẹ tí ẹ ó máa tẹ̀ lé nígbà Ìrékọjá nìyí: Àjèjì kankan ò gbọ́dọ̀ jẹ nínú rẹ̀.+

  • Diutarónómì 14:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ òkú ẹran èyíkéyìí.+ Ẹ lè fún àjèjì tó wà nínú àwọn ìlú* yín, kó sì jẹ ẹ́ tàbí kí ẹ tà á fún àjèjì. Torí pé èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín.

      “Ẹ ò gbọ́dọ̀ se ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá rẹ̀.+

  • Diutarónómì 23:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 O lè gba èlé lọ́wọ́ àjèjì,+ àmọ́ o ò gbọ́dọ̀ gba èlé lọ́wọ́ arákùnrin rẹ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run rẹ lè máa bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o bá dáwọ́ lé ní ilẹ̀ tí o fẹ́ lọ gbà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́