Jòhánù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìrékọjá+ àwọn Júù ti sún mọ́lé, Jésù sì gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù. Jòhánù 11:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ìrékọjá+ àwọn Júù ti sún mọ́lé, ọ̀pọ̀ èèyàn láti ìgbèríko sì gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù kó tó dìgbà Ìrékọjá kí wọ́n lè wẹ ara wọn mọ́ bí Òfin ṣe sọ.
55 Ìrékọjá+ àwọn Júù ti sún mọ́lé, ọ̀pọ̀ èèyàn láti ìgbèríko sì gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù kó tó dìgbà Ìrékọjá kí wọ́n lè wẹ ara wọn mọ́ bí Òfin ṣe sọ.