-
Léfítíkù 23:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘Kí ẹ ka sábáàtì méje láti ọjọ́ tó tẹ̀ lé Sábáàtì, láti ọjọ́ tí ẹ mú ìtí ọrẹ fífì+ náà wá. Kí ọjọ́ àwọn ọ̀sẹ̀ náà pé.