-
Diutarónómì 13:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 O gbọ́dọ̀ sọ ọ́ lókùúta pa,+ torí ó fẹ́ mú ọ kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ẹni tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú.
-