1 Sámúẹ́lì 7:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+ 16 Lọ́dọọdún, ó máa ń rin ìrìn àjò yí ká Bẹ́tẹ́lì,+ Gílígálì+ àti Mísípà,+ ó sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ibí yìí.
15 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+ 16 Lọ́dọọdún, ó máa ń rin ìrìn àjò yí ká Bẹ́tẹ́lì,+ Gílígálì+ àti Mísípà,+ ó sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ibí yìí.