1 Sámúẹ́lì 7:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Sámúẹ́lì wá sọ pé: “Ẹ kó gbogbo Ísírẹ́lì jọ sí Mísípà,+ màá sì gbàdúrà sí Jèhófà nítorí yín.”+