Nọ́ńbà 35:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìlú mẹ́fà yìí máa jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àjèjì+ àtàwọn tí wọ́n jọ ń gbé, ibẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó bá ṣèèṣì pa èèyàn*+ máa sá wọ̀. Diutarónómì 4:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Tí apààyàn èyíkéyìí bá ṣèèṣì pa ọmọnìkejì rẹ̀, tí kì í sì í ṣe pé ó kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀,+ kó sá lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú yìí, kí wọ́n má bàa pa á.+
15 Ìlú mẹ́fà yìí máa jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àjèjì+ àtàwọn tí wọ́n jọ ń gbé, ibẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó bá ṣèèṣì pa èèyàn*+ máa sá wọ̀.
42 Tí apààyàn èyíkéyìí bá ṣèèṣì pa ọmọnìkejì rẹ̀, tí kì í sì í ṣe pé ó kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀,+ kó sá lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú yìí, kí wọ́n má bàa pa á.+