Nọ́ńbà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì. Nọ́ńbà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 A rí àwọn Néfílímù níbẹ̀, àwọn ọmọ Ánákì,+ tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ* àwọn Néfílímù. Lójú wọn, ṣe la dà bíi tata, bẹ́ẹ̀ náà ló sì rí lójú tiwa.”
22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.
33 A rí àwọn Néfílímù níbẹ̀, àwọn ọmọ Ánákì,+ tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ* àwọn Néfílímù. Lójú wọn, ṣe la dà bíi tata, bẹ́ẹ̀ náà ló sì rí lójú tiwa.”