-
Léfítíkù 21:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “‘Tí ọmọbìnrin àlùfáà bá ṣe aṣẹ́wó, tó tipa bẹ́ẹ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́, bàbá rẹ̀ ló sọ di aláìmọ́. Kí ẹ fi iná sun+ ọmọbìnrin náà.
-