-
Nehemáyà 5:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Yàtọ̀ síyẹn, èmi àti àwọn arákùnrin mi pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ mi ń yá wọn ní owó àti ọkà. Ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ ká jáwọ́ nínú gbígba èlé lórí ohun tí a yáni.+
-