-
Ẹ́kísódù 23:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Tí aláìní kan láàárín yín bá ní ẹjọ́, má ṣe yí ìdájọ́ rẹ̀ po.+
-
-
2 Kíróníkà 19:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó sọ fún àwọn onídàájọ́ náà pé: “Ẹ fiyè sí ohun tí ẹ̀ ń ṣe, nítorí kì í ṣe èèyàn lẹ̀ ń ṣojú fún tí ẹ bá ń dájọ́, Jèhófà ni, ó sì wà pẹ̀lú yín nígbà tí ẹ bá ń ṣe ìdájọ́.+
-
-
Òwe 17:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ẹni tó bá dá ẹni burúkú láre àti ẹni tó dá olódodo lẹ́bi+
Àwọn méjèèjì jẹ́ ẹni ìkórìíra lójú Jèhófà.
-