Léfítíkù 19:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Kí ẹ máa lo òṣùwọ̀n tó péye, ìwọ̀n tó péye, òṣùwọ̀n tó péye fún ohun tí kò lómi* àti òṣùwọ̀n tó péye fún nǹkan olómi.*+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
36 Kí ẹ máa lo òṣùwọ̀n tó péye, ìwọ̀n tó péye, òṣùwọ̀n tó péye fún ohun tí kò lómi* àti òṣùwọ̀n tó péye fún nǹkan olómi.*+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, ẹni tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.